Fidio Yorùbá yìí yóò ṣe àfihàn Ìkànìyàn ọdún Twenty twenty fún ọ, yóò fi ìwò l’ápapọ̀ ní kíákíá nípa ìwé ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò lórí ayélujára hàn, ti yóò sì ràn ọ lọ́wọ́ láti dáhùn ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.
All video content created by the U.S. Census Bureau is available on our YouTube channel. Subscribe to get notifications when new content is uploaded.